Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 118:27-29 BIBELI MIMỌ (BM)

27. OLUWA ni Ọlọrun, ó sì ti tan ìmọ́lẹ̀ sí wa.Pẹlu ẹ̀ka igi lọ́wọ́, ẹ bẹ̀rẹ̀ ayẹyẹ ìwọ́de ẹbọ náà,títí dé ibi ìwo pẹpẹ.

28. Ìwọ ni Ọlọrun mi,n óo máa dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ.Ìwọ ni Ọlọrun mi,n óo máa gbé ọ ga.

29. Ẹ dúpẹ́ lọ́wọ́ OLUWA, nítorí pé ó ṣeun,nítorí pé ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí lae.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 118