Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 113:5-8 BIBELI MIMỌ (BM)

5. Ta ló dàbí OLUWA Ọlọrun wa,tí ó gúnwà sí òkè ọ̀run,

6. ẹni tí ó bojú wo ilẹ̀láti wo ọ̀run ati ayé?

7. Ó gbé talaka dìde láti inú erùpẹ̀,ó sì gbé aláìní sókè láti orí eérú,

8. láti mú wọn jókòó láàrin àwọn ìjòyè,àní, àwọn ìjòyè àwọn eniyan rẹ̀.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 113