Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 111:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìbẹ̀rù OLUWA ni ìbẹ̀rẹ̀ ọgbọ́n,gbogbo àwọn tí ó bá ń tẹ̀lé ìlànà rẹ̀, á máa ní ìmọ̀ pípé.Títí lae ni ìyìn rẹ̀.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 111

Wo Orin Dafidi 111:10 ni o tọ