Yóo ṣe ìdájọ́ àwọn orílẹ̀-èdè,ọpọlọpọ òkú ni yóo sì sùn ninu wọn;yóo sì run àwọn ìjòyè káàkiri ilẹ̀ ayé.