Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 110:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. OLUWA wí fún oluwa mi, ọba, pé,“Jókòó sí apá ọ̀tún mi,títí tí n óo fi sọ àwọn ọ̀tá rẹdi àpótí ìtìsẹ̀ rẹ.”

2. OLUWA yóo na ọ̀pá àṣẹ rẹ tí ó lágbára láti Sioni.O óo jọba láàrin àwọn ọ̀tá rẹ.

3. Àwọn eniyan rẹ yóo fi tọkàntọkàn fa ara wọn kalẹ̀,lọ́jọ́ tí o bá ń kó àwọn ọmọ ogun rẹ jọ lórí òkè mímọ́.Àwọn ọ̀dọ́ yóo jáde tọ̀ ọ́ wá bí ìrì òwúrọ̀.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 110