Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 109:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Má dákẹ́, ìwọ Ọlọrun tí mò ń yìn.

2. Nítorí pé ẹnu àwọn eniyan burúkú ati tiàwọn ẹlẹ́tàn kò dákẹ́,wọ́n ń sọ̀rọ̀ èké nípa mi.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 109