Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 108:2-6 BIBELI MIMỌ (BM)

2. Ẹ jí ẹ̀yin ohun èlò ìkọrin ati hapu!Èmi fúnra mi náà yóo jí ní òwúrọ̀ kutukutu,

3. OLUWA, n óo máa dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ láàrin àwọn eniyan,n óo sì máa kọrin ìyìn sí ọ láàrin àwọn orílẹ̀-èdè.

4. Nítorí pé ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ tóbi, ó ga ju ọ̀run lọ,òtítọ́ rẹ sì kan ojú ọ̀run.

5. Kí á gbé ọ ga ju ọ̀run lọ, Ọlọrun,kí ògo rẹ sì kárí gbogbo ayé.

6. Kí á lè gba àyànfẹ́ rẹ là,fi ọwọ́ agbára rẹ gbà wá, kí o sì dá mi lóhùn.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 108