Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 108:10-13 BIBELI MIMỌ (BM)

10. Ta ni yóo mú mi wọ inú ìlú olódi náà?Ta ni yóo mú mi lọ sí Edomu?

11. Ọlọrun, o kò ha ti kọ̀ wá sílẹ̀?Ọlọrun, o ò bá àwọn ọmọ ogun wa lọ sójú ogun mọ́.

12. Ràn wá lọ́wọ́, bá wa gbógun ti àwọn ọ̀tá wa,nítorí pé asán ni ìrànlọ́wọ́ eniyan.

13. Pẹlu àtìlẹ́yìn Ọlọ́run, a óo ṣe akin;nítorí òun ni yóo tẹ àwọn ọ̀tá wa mọ́lẹ̀.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 108