Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Orin Dafidi 100:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ẹ hó ìhó ayọ̀ sí OLUWA, gbogbo ilẹ̀ ayé.

2. Ẹ fi ayọ̀ sin OLUWA.Ẹ wá siwaju rẹ̀ pẹlu orin ayọ̀.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 100