Ìwọ ìlú Temani,ìbẹ̀rùbojo yóo dé bá àwọn akọni rẹ,gbogbo àwọn ọkunrin tí wọ́n wà ní òkè Esau ni a óo sì fi idà pa.