Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ọbadaya 1:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Ilé Jakọbu yóo dàbí iná,ilé Josẹfu yóo dàbí ọ̀wọ́ iná,ilé Esau yóo sì dàbí àgékù koríko.Wọn yóo jó ilé Esau;àwọn ìran Esau yóo jó àjórun láìku ẹnìkan;nítorí pé OLUWA ló sọ bẹ́ẹ̀.

Ka pipe ipin Ọbadaya 1

Wo Ọbadaya 1:18 ni o tọ