Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọmba 9:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà mìíràn, ìkùukùu náà lè má dúró lórí Àgọ́ Àjọ ju àṣáálẹ́ títí di òwúrọ̀ lọ, sibẹsibẹ, nígbàkúùgbà tí ìkùukùu bá kúrò lórí Àgọ́ Àjọ ni àwọn ọmọ Israẹli máa ń tẹ̀síwájú.

Ka pipe ipin Nọmba 9

Wo Nọmba 9:21 ni o tọ