Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọmba 8:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí wọ́n mú akọ mààlúù kékeré kan ati ìyẹ̀fun kíkúnná tí a fi òróró pò fún ẹbọ ohun jíjẹ wá. Kí wọ́n sì mú akọ mààlúù kékeré mìíràn wá, fún ẹbọ ìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀.

Ka pipe ipin Nọmba 8

Wo Nọmba 8:8 ni o tọ