Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọmba 8:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn tí o bá ti wẹ̀ wọ́n mọ́, tí o sì ti yà wọ́n sọ́tọ̀ bí ẹbọ fífì sí OLUWA, ni àwọn ọmọ Lefi tó lè ṣiṣẹ́ ninu Àgọ́ Àjọ.

Ka pipe ipin Nọmba 8

Wo Nọmba 8:15 ni o tọ