Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọmba 7:87 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo mààlúù tí wọ́n mú wá fún ọrẹ ẹbọ sísun jẹ́ mejila ati àgbò mejila, ọ̀dọ́ àgbò mejila ọlọ́dún kọ̀ọ̀kan, pẹlu ẹbọ ohun jíjẹ. Wọ́n tún mú òbúkọ mejila wá fún ẹbọ ìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀.

Ka pipe ipin Nọmba 7

Wo Nọmba 7:87 ni o tọ