Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọmba 7:3 BIBELI MIMỌ (BM)

mú ọrẹ ẹbọ wá siwaju OLUWA. Ọkọ̀ ẹrù mẹfa ati akọ mààlúù mejila. Ọkọ̀ ẹrù kọ̀ọ̀kan fún olórí meji meji, ati akọ mààlúù kọ̀ọ̀kan fún olórí kọ̀ọ̀kan. Wọ́n mú àwọn ẹbọ wọnyi wá sí ẹnu ọ̀nà ibi mímọ́.

Ka pipe ipin Nọmba 7

Wo Nọmba 7:3 ni o tọ