Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọmba 7:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó sì mú akọ mààlúù meji, àgbò marun-un, òbúkọ marun-un ati ọ̀dọ́ àgbò marun-un ọlọ́dún kọ̀ọ̀kan wá fún ẹbọ alaafia. Wọ́n jẹ́ ọrẹ Netaneli ọmọ Suari.

Ka pipe ipin Nọmba 7

Wo Nọmba 7:23 ni o tọ