Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọmba 5:2 BIBELI MIMỌ (BM)

“Pàṣẹ fún àwọn ọmọ Israẹli kí wọ́n lé gbogbo àwọn adẹ́tẹ̀ kúrò ní ibùdó wọn, gbogbo àwọn tí ó ni ọyún lára ati ẹnikẹ́ni tí ó di aláìmọ́ nípa fífi ọwọ́ kan òkú.

Ka pipe ipin Nọmba 5

Wo Nọmba 5:2 ni o tọ