Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọmba 35:23 BIBELI MIMỌ (BM)

tabi bí ẹnìkan bá ṣèèṣì sọ òkúta láì wo ibi tí ó sọ òkúta náà sí, tí òkúta náà sì pa eniyan tí kì í ṣe pé ó ti fẹ́ pa olúwarẹ̀ tẹ́lẹ̀, tí kò sì kórìíra rẹ̀,

Ka pipe ipin Nọmba 35

Wo Nọmba 35:23 ni o tọ