Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọmba 35:2 BIBELI MIMỌ (BM)

“Pàṣẹ fún àwọn ọmọ Israẹli pé ninu ilẹ̀ ìní wọn, kí wọ́n fún àwọn ọmọ Lefi ní àwọn ìlú tí wọn yóo máa gbé, kí wọ́n sì fún wọn ní ilẹ̀ pápá yíká àwọn ìlú wọnyi.

Ka pipe ipin Nọmba 35

Wo Nọmba 35:2 ni o tọ