Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọmba 35:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọn yóo jẹ́ ìlú ààbò fún àwọn ọmọ Israẹli tabi àwọn àlejò tí ó wà láàrin wọn. Ẹnikẹ́ni tí ó bá ṣèèṣì paniyan lè sá lọ sibẹ.

Ka pipe ipin Nọmba 35

Wo Nọmba 35:15 ni o tọ