Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọmba 34:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Yóo sì yí láti ìhà gúsù lọ sí gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ òkè Akirabimu, yóo sì la aṣálẹ̀ Sini kọjá lọ títí dé ìhà gúsù Kadeṣi Banea ati títí dé Hasari Adari ati títí dé Asimoni.

Ka pipe ipin Nọmba 34

Wo Nọmba 34:4 ni o tọ