Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọmba 34:19-22 BIBELI MIMỌ (BM)

19. Àwọn olórí náà nìwọ̀nyí: láti inú ẹ̀yà Juda, a yan Kalebu ọmọ Jefune.

20. Láti inú ẹ̀yà Simeoni, a yan Ṣemueli ọmọ Amihudu.

21. Láti inú ẹ̀yà Bẹnjamini, a yan Elidadi ọmọ Kisiloni.

22. Láti inú ẹ̀yà Dani, a yan Buki ọmọ Jogili.

Ka pipe ipin Nọmba 34