Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọmba 33:31-35 BIBELI MIMỌ (BM)

31. Láti Moserotu wọ́n lọ sí Bene Jaakani.

32. Láti Bene Jaakani wọ́n lọ sí Hori Hagidigadi.

33. Láti Hori Hagidigadi wọ́n lọ sí Jotibata.

34. Láti Jotibata wọ́n lọ sí Abirona.

35. Láti Abirona wọ́n lọ sí Esiongeberi.

Ka pipe ipin Nọmba 33