Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọmba 33:25-37 BIBELI MIMỌ (BM)

25. Láti Harada wọ́n lọ sí Makihelotu.

26. Láti Makihelotu wọ́n lọ sí Tahati.

27. Láti Tahati wọ́n lọ sí Tẹra.

28. Láti Tẹra wọ́n lọ sí Mitika.

29. Láti Mitika wọ́n lọ sí Haṣimona.

30. Láti Haṣimona wọ́n lọ sí Moserotu.

31. Láti Moserotu wọ́n lọ sí Bene Jaakani.

32. Láti Bene Jaakani wọ́n lọ sí Hori Hagidigadi.

33. Láti Hori Hagidigadi wọ́n lọ sí Jotibata.

34. Láti Jotibata wọ́n lọ sí Abirona.

35. Láti Abirona wọ́n lọ sí Esiongeberi.

36. Láti Esiongeberi wọ́n lọ sí aṣálẹ̀ Sini, tíí ṣe Kadeṣi.

37. Láti Kadeṣi wọ́n lọ sí Òkè Hori, lẹ́bàá ilẹ̀ Edomu.

Ka pipe ipin Nọmba 33