Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọmba 33:20-24 BIBELI MIMỌ (BM)

20. Láti Rimoni Peresi wọ́n lọ sí Libina.

21. Láti Libina wọ́n lọ sí Risa.

22. Láti Risa wọ́n lọ sí Kehelata.

23. Láti Kehelata wọ́n lọ sí Òkè Ṣeferi.

24. Láti Òkè Ṣeferi wọ́n lọ sí Harada.

Ka pipe ipin Nọmba 33