Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọmba 31:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣé ẹ ranti pé àwọn ni wọ́n tẹ̀lé ìmọ̀ràn Balaamu tí wọ́n sì mú àwọn ọmọ Israẹli ṣẹ̀ sí OLUWA ní Peori, nítorí ẹ̀ṣẹ̀ yìí ni àjàkálẹ̀ àrùn ṣe bẹ́ sílẹ̀ láàrin àwọn ọmọ Israẹli?

Ka pipe ipin Nọmba 31

Wo Nọmba 31:16 ni o tọ