Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọmba 31:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. OLUWA sọ fún Mose pé,

2. “Fìyà jẹ àwọn ará Midiani fún ohun tí wọ́n ṣe sí àwọn ọmọ Israẹli. Lẹ́yìn náà, o óo kú.”

Ka pipe ipin Nọmba 31