Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọmba 3:26 BIBELI MIMỌ (BM)

aṣọ tí wọ́n ń ta sí àgbàlá, aṣọ tí wọ́n ń ta sí ẹnu ọ̀nà àbáwọ àgbàlá tí ó yí ibi mímọ́ ati pẹpẹ ká, ati okùn, ati gbogbo nǹkan tí wọ́n ń lò pẹlu rẹ̀.

Ka pipe ipin Nọmba 3

Wo Nọmba 3:26 ni o tọ