Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọmba 29:26 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ní ọjọ́ karun-un, ẹ óo máa fi ẹgbọ̀rọ̀ akọ mààlúù mẹsan-an, àgbò meji ati ọ̀dọ́ àgbò mẹrinla ọlọ́dún kọ̀ọ̀kan, tí kò ní àbààwọ́n rúbọ.

Ka pipe ipin Nọmba 29

Wo Nọmba 29:26 ni o tọ