Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọmba 29:19 BIBELI MIMỌ (BM)

pẹlu òbúkọ kan fún ẹbọ ìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀. Ẹ óo máa rú ẹbọ wọnyi kún ẹbọ sísun ati ẹbọ ohun jíjẹ ati ẹbọ ohun mímu ojoojumọ.

Ka pipe ipin Nọmba 29

Wo Nọmba 29:19 ni o tọ