Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọmba 29:11 BIBELI MIMỌ (BM)

ati òbúkọ kan fún ẹbọ ìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀ láti ṣe ètùtù fun yín. Ẹ óo tún fi òbúkọ mìíràn rú ẹbọ ìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀ fún ètùtù, ẹ óo sì rú ẹbọ sísun ati ẹbọ ohun jíjẹ ati ẹbọ ohun mímu ojoojumọ pẹlu.”

Ka pipe ipin Nọmba 29

Wo Nọmba 29:11 ni o tọ