Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọmba 27:22-23 BIBELI MIMỌ (BM)

22. Mose ṣe gbogbo ohun tí OLUWA pa láṣẹ fún un. Ó mú Joṣua wá siwaju Eleasari alufaa ati gbogbo àwọn eniyan,

23. ó gbé ọwọ́ rẹ̀ lé e lórí, ó sì fún un ní àṣẹ.

Ka pipe ipin Nọmba 27