Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọmba 26:54 BIBELI MIMỌ (BM)

Fún àwọn tí ó pọ̀ ní ilẹ̀ pupọ ati àwọn tí ó kéré ní ilẹ̀ kéékèèké. Bí iye eniyan tí ó wà ninu ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan bá ti pọ̀ sí ni kí ẹ fi pín ilẹ̀ náà fún wọn.

Ka pipe ipin Nọmba 26

Wo Nọmba 26:54 ni o tọ