Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọmba 25:11 BIBELI MIMỌ (BM)

“N kò ní bínú sí Israẹli mọ nítorí ohun tí Finehasi ọmọ Eleasari, ọmọ Aaroni, alufaa, ṣe. Ó kọ̀ láti gba ìbọ̀rìṣà láàyè, nítorí náà ni n kò ṣe ní fi ibinu pa àwọn ọmọ Israẹli run.

Ka pipe ipin Nọmba 25

Wo Nọmba 25:11 ni o tọ