Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọmba 24:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìran ẹni tí ó ń gbọ́ ọ̀rọ̀ Ọlọrun,tí ó ní ìmọ̀ ẹni tí ó ga jùlọ,tí ó sì ń rí ìran láti ọ̀dọ̀ Olodumare.Nítòótọ́ ó ṣubú, ṣugbọn ojú rẹ̀ kò wà ní dídì.

Ka pipe ipin Nọmba 24

Wo Nọmba 24:16 ni o tọ