Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọmba 24:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Balaki bá bínú sí Balaamu gidigidi, ó bẹ̀rẹ̀ sí fi ọwọ́ lu ọwọ́. Ó sì sọ fún Balaamu pé: “Mo pè ọ́ pé kí o wá gbé àwọn ọ̀tá mi ṣépè, ṣugbọn dípò kí o gbé wọ́n ṣépè, o súre fún wọn ní ìgbà mẹta!

Ka pipe ipin Nọmba 24

Wo Nọmba 24:10 ni o tọ