Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọmba 22:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Balaamu sọ fún wọn pé, “Ẹ sùn níbí ní alẹ́ yìí, bí ó bá di ọ̀la, n óo sọ ohun tí OLUWA bá sọ fún mi fun yín.” Àwọn àgbààgbà náà sì dúró lọ́dọ̀ Balaamu.

Ka pipe ipin Nọmba 22

Wo Nọmba 22:8 ni o tọ