Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọmba 22:41 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní òwúrọ̀ ọjọ́ keji, Balaki mú Balaamu lọ sí ibi gegele Bamotu Baali níbi tí ó ti lè rí apá kan àwọn ọmọ Israẹli.

Ka pipe ipin Nọmba 22

Wo Nọmba 22:41 ni o tọ