Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọmba 22:36 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Balaki gbọ́ pé Balaamu ń bọ̀, ó jáde lọ pàdé rẹ̀ ní ìlú Moabu tí ó wà létí odò Arinoni ní ààlà ilẹ̀ Moabu.

Ka pipe ipin Nọmba 22

Wo Nọmba 22:36 ni o tọ