Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọmba 22:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni OLUWA la Balaamu lójú láti rí angẹli tí ó dúró lójú ọ̀nà pẹlu idà lọ́wọ́ rẹ̀, Balaamu sì dojúbolẹ̀.

Ka pipe ipin Nọmba 22

Wo Nọmba 22:31 ni o tọ