Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọmba 22:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ náà rí angẹli náà, ó wó lulẹ̀ lábẹ́ Balaamu. Inú bí Balaamu gidigidi, ó sì fi ọ̀pá rẹ̀ na kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ náà.

Ka pipe ipin Nọmba 22

Wo Nọmba 22:27 ni o tọ