Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọmba 22:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní òru ọjọ́ náà, Ọlọrun tọ Balaamu wá, ó ní, “Bí ó bá jẹ́ pé àwọn ọkunrin wọnyi wá bẹ̀ ọ́ pé kí o bá wọn lọ, máa bá wọn lọ, ṣugbọn ohun tí mo bá sọ fún ọ ni o gbọdọ̀ ṣe.”

Ka pipe ipin Nọmba 22

Wo Nọmba 22:20 ni o tọ