Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọmba 21:35 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ Israẹli pa Ogu ati àwọn ọmọ rẹ̀ ati gbogbo eniyan rẹ̀. Wọn kò dá ẹnìkan sí, wọ́n sì gba ilẹ̀ wọn.

Ka pipe ipin Nọmba 21

Wo Nọmba 21:35 ni o tọ