Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọmba 20:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn ará Edomu kò jẹ́ kí àwọn ọmọ Israẹli gba ilẹ̀ wọn kọjá, wọ́n bá gba ọ̀nà ibòmíràn.

Ka pipe ipin Nọmba 20

Wo Nọmba 20:21 ni o tọ