Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọmba 2:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, Àgọ́ Ẹ̀rí yóo ṣí, pẹlu àgọ́ àwọn ọmọ Lefi. Bí wọ́n ti pàgọ́ yí Àgọ́ náà ká, bẹ́ẹ̀ ni wọn yóo ṣe máa ṣí, olukuluku ní ipò rẹ̀, pẹlu àsíá ẹ̀yà rẹ̀.

Ka pipe ipin Nọmba 2

Wo Nọmba 2:17 ni o tọ