Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọmba 18:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn àwọn ọmọ Lefi nìkan ni yóo máa ṣiṣẹ́ ninu Àgọ́ Àjọ, wọn óo sì ru ẹ̀ṣẹ̀ wọn. Ìlànà ayérayé ni èyí fún arọmọdọmọ yín, wọn kò tún gbọdọ̀ ní ohun ìní kan mọ́, láàrin àwọn ọmọ Israẹli;

Ka pipe ipin Nọmba 18

Wo Nọmba 18:23 ni o tọ