Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọmba 18:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Pe àwọn eniyan rẹ, àwọn ọmọ Lefi, ẹ̀yà ìdílé baba rẹ, pé kí wọn wà pẹlu rẹ, kí wọ́n sì máa jíṣẹ́ fún ọ nígbà tí ìwọ ati àwọn ọmọ rẹ bá ń ṣiṣẹ́ ninu Àgọ́ Ẹ̀rí.

Ka pipe ipin Nọmba 18

Wo Nọmba 18:2 ni o tọ