Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọmba 18:19 BIBELI MIMỌ (BM)

“Gbogbo àwọn ẹbọ mímọ́ tí àwọn ọmọ Israẹli bá mú wá fún mi ni mo fún ìwọ ati àwọn ọmọ rẹ, lọkunrin ati lobinrin, gẹ́gẹ́ bí ìpín wọn títí lae. Èyí jẹ́ majẹmu pataki tí mo bá ìwọ ati àwọn ọmọ rẹ dá.”

Ka pipe ipin Nọmba 18

Wo Nọmba 18:19 ni o tọ