Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Nọmba 18:15 BIBELI MIMỌ (BM)

“Gbogbo àwọn àkọ́bí eniyan tabi ti ẹranko tí àwọn ọmọ Israẹli bá mú wá fún mi, tìrẹ ni. Ṣugbọn o óo gba owó ìràpadà dípò àkọ́bí eniyan ati ti ẹranko tí ó bá jẹ́ aláìmọ́.

Ka pipe ipin Nọmba 18

Wo Nọmba 18:15 ni o tọ